-
Léfítíkù 27:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Èyí ni àwọn àṣẹ tí Jèhófà pa fún Mósè ní Òkè Sínáì+ pé kó sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
-
-
Diutarónómì 6:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Èyí ni àwọn àṣẹ, ìlànà àti ìdájọ́ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fi lélẹ̀ láti kọ́ yín, kí ẹ lè máa pa wọ́n mọ́ tí ẹ bá ti sọdá sí ilẹ̀ tí ẹ máa gbà,
-