Ẹ́kísódù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ Nọ́ńbà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì,+ nínú àgọ́ ìpàdé,+ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ó sọ pé:
3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+
1 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì,+ nínú àgọ́ ìpàdé,+ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ó sọ pé: