-
Léfítíkù 23:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ kí ẹ ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà fún ọjọ́ méje. Ní ọjọ́ keje, àpéjọ mímọ́ máa wà. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.’”
-
-
Diutarónómì 16:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí o fi jẹ búrẹ́dì aláìwú, àpéjọ ọlọ́wọ̀ sì máa wà fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ ní ọjọ́ keje. O ò gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́ kankan.+
-