-
Ẹ́kísódù 14:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n ṣẹ́rí pa dà, kí wọ́n sì pàgọ́ síwájú Píháhírótì, láàárín Mígídólì àti òkun, níbi tí wọ́n á ti máa rí Baali-séfónì lọ́ọ̀ọ́kán.+ Kí ẹ pàgọ́ síbi tó dojú kọ ọ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun.
-