- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 13:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        26 Wọ́n sì pa dà sọ́dọ̀ Mósè àti Áárónì àti gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní aginjù Páránì, ní Kádéṣì.+ Wọ́n jábọ̀ fún gbogbo àpéjọ náà, wọ́n sì fi àwọn èso ilẹ̀ náà hàn wọ́n. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 32:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Ohun tí àwọn bàbá yín ṣe nìyẹn nígbà tí mo rán wọn láti Kadeṣi-báníà pé kí wọ́n lọ wo ilẹ̀+ náà. 
 
-