ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 30:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ọlọ́run fetí sí Líà, ó sì dá a lóhùn, ó lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin karùn-ún fún Jékọ́bù. 18 Líà sì sọ pé: “Ọlọ́run ti pín mi lérè,* torí mo ti fún ọkọ mi ní ìránṣẹ́ mi.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ísákà.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 46:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àwọn ọmọ Ísákà ni Tólà, Púfà, Íóbù àti Ṣímúrónì.+

  • Nọ́ńbà 2:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Kí ẹ̀yà Ísákà pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ wọn; Nétánélì+ ọmọ Súárì ni ìjòyè àwọn ọmọ Ísákà. 6 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnléláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (54,400).+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́