-
Jẹ́nẹ́sísì 35:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọmọkùnrin tí Líà bí ni Rúbẹ́nì+ tó jẹ́ àkọ́bí Jékọ́bù, lẹ́yìn náà, ó bí Síméónì, Léfì, Júdà, Ísákà àti Sébúlúnì.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 46:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àwọn ọmọ Ísákà ni Tólà, Púfà, Íóbù àti Ṣímúrónì.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 49:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Ísákà+ jẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí egungun rẹ̀ le, tó dùbúlẹ̀ sáàárín àpò ẹrù méjì tí wọ́n so mọ́ ẹ̀yìn rẹ̀.
-