-
Nọ́ńbà 2:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Kí ẹ̀yà Áṣérì pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ wọn; Págíẹ́lì+ ọmọ Ókíránì ni ìjòyè àwọn ọmọ Áṣérì.
-
-
Nọ́ńbà 10:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Págíẹ́lì+ ọmọ Ókíránì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì.
-