- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 7:72Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        72 Ní ọjọ́ kọkànlá, Págíẹ́lì+ ọmọ Ókíránì, ìjòyè àwọn ọmọ Áṣérì 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 10:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        26 Págíẹ́lì+ ọmọ Ókíránì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì. 
 
-