Jẹ́nẹ́sísì 29:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, ọkọ mi yóò fà mọ́ mi, torí mo ti bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún un.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Léfì.*+ Jẹ́nẹ́sísì 46:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ọmọ Léfì+ ni Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Nọ́ńbà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi.
34 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, ọkọ mi yóò fà mọ́ mi, torí mo ti bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún un.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Léfì.*+
12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi.