Jẹ́nẹ́sísì 34:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+ Jẹ́nẹ́sísì 49:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Tẹ̀gbọ́n-tàbúrò+ ni Síméónì àti Léfì. Ohun èlò ìwà ipá ni ohun ìjà wọn.+ Ẹ́kísódù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137). Nọ́ńbà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi. 1 Kíróníkà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọmọ Léfì+ ni Gẹ́ṣónì, Kóhátì+ àti Mérárì.+
25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+
16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).
12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi.