-
Léfítíkù 16:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Kí ẹni tó fi iná sun ún fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, lẹ́yìn náà ó lè wá sínú ibùdó.
-
-
Nọ́ńbà 19:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kí àlùfáà wá fọ aṣọ rẹ̀, kó sì fi omi wẹ ara rẹ̀,* lẹ́yìn náà, ó lè wá sínú ibùdó; àmọ́ àlùfáà náà máa jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.
-