ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 1:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Kí o yan àwọn ọmọ Léfì láti máa bójú tó àgọ́ Ẹ̀rí+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo ohun tó jẹ́ ti àgọ́ náà.+ Kí wọ́n máa gbé àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀,+ kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ níbẹ̀,+ kí wọ́n sì pàgọ́ yí àgọ́ ìjọsìn+ náà ká.

  • Nọ́ńbà 3:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Jẹ́ kí ẹ̀yà Léfì+ wá síwájú, kí o sì ní kí wọ́n dúró níwájú àlùfáà Áárónì, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́+ fún un.

  • 2 Kíróníkà 31:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nígbà náà, Hẹsikáyà yan àwọn àlùfáà sí àwùjọ wọn,+ ó sì yan àwọn ọmọ Léfì sí àwùjọ wọn,+ ó yan ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì sẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn,+ láti máa rú ẹbọ sísun, kí wọ́n sì máa rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́, kí wọ́n máa dúpẹ́, kí wọ́n sì máa yin Ọlọ́run ní àwọn ẹnubodè tó wà ní àwọn àgbàlá* Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́