Nọ́ńbà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí Áárónì mú àwọn ọmọ Léfì wá* síwájú Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fífì+ láti ọwọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n sì máa ṣiṣẹ́ Jèhófà.+
11 Kí Áárónì mú àwọn ọmọ Léfì wá* síwájú Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fífì+ láti ọwọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n sì máa ṣiṣẹ́ Jèhófà.+