- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 18:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        15 Mósè sọ fún bàbá ìyàwó rẹ̀ pé: “Torí pé àwọn èèyàn ń wá sọ́dọ̀ mi kí n lè bá wọn wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ Ọlọ́run ni. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 15:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        33 Àwọn tó rí i níbi tó ti ń ṣa igi wá mú un lọ sọ́dọ̀ Mósè àti Áárónì àti gbogbo àpéjọ náà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 27:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Àwọn ọmọ Sélóféhádì+ wá sí tòsí, Sélóféhádì yìí ni ọmọ Héfà, ọmọ Gílíádì, ọmọ Mákírù, ọmọ Mánásè, látọ̀dọ̀ àwọn ìdílé Mánásè ọmọ Jósẹ́fù. Orúkọ àwọn ọmọ Sélóféhádì ni Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tírísà. 2 Wọ́n dúró síwájú Mósè, àlùfáà Élíásárì, àwọn ìjòyè+ àti gbogbo àpéjọ náà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, wọ́n sì sọ pé: 
 
-