Nọ́ńbà 9:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìgbàkígbà tí ìkùukùu náà bá kúrò lórí àgọ́ náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì á gbéra+ kíákíá, ibi tí ìkùukùu náà bá sì dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa pàgọ́+ sí. Sáàmù 78:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó fi ìkùukùu* ṣamọ̀nà wọn ní ọ̀sán,Ó sì fi ìmọ́lẹ̀ iná ṣamọ̀nà wọn ní gbogbo òru.+
17 Ìgbàkígbà tí ìkùukùu náà bá kúrò lórí àgọ́ náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì á gbéra+ kíákíá, ibi tí ìkùukùu náà bá sì dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa pàgọ́+ sí.