Nọ́ńbà 1:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀. 5 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa dúró tì yín nìyí: ní ẹ̀yà Rúbẹ́nì, Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì; Nọ́ńbà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì+ wà ní apá gúúsù, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀. 5 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa dúró tì yín nìyí: ní ẹ̀yà Rúbẹ́nì, Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì;
10 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì+ wà ní apá gúúsù, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.