- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 1:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 ní ẹ̀yà Dánì, Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì; 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 2:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        31 “Gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú ibùdó Dánì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàdínlọ́gọ́jọ ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (157,600). Àwọn ni kó máa tú àgọ́ wọn ká kẹ́yìn,+ bí wọ́n ṣe pín ẹ̀yà wọn ní mẹ́ta-mẹ́ta.” 
 
-