Nọ́ńbà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Dánì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* àwọn ni wọ́n wà lẹ́yìn tí wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ibùdó náà. Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni olórí àwùjọ náà.
25 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Dánì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* àwọn ni wọ́n wà lẹ́yìn tí wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ibùdó náà. Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni olórí àwùjọ náà.