ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àlùfáà Mídíánì+ ní ọmọbìnrin méje, àwọn ọmọ yìí wá fa omi, wọ́n sì pọnmi kún àwọn ọpọ́n ìmumi kí wọ́n lè fún agbo ẹran bàbá wọn lómi.

  • Ẹ́kísódù 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbà tí wọ́n dé ilé lọ́dọ̀ Réúẹ́lì*+ bàbá wọn, ó yà á lẹ́nu, ó sì bi wọ́n pé: “Kí ló mú kí ẹ tètè pa dà sílé lónìí?”

  • Ẹ́kísódù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+

  • Ẹ́kísódù 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Jẹ́tírò àlùfáà Mídíánì, bàbá ìyàwó Mósè+ gbọ́ nípa gbogbo ohun tí Ọlọ́run ti ṣe fún Mósè àti fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ èèyàn rẹ̀, bí Jèhófà ṣe mú Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì.+

  • Ẹ́kísódù 18:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Jẹ́tírò, bàbá ìyàwó Mósè, pẹ̀lú àwọn ọmọ Mósè àti ìyàwó rẹ̀ wá bá Mósè ní aginjù níbi tó pàgọ́ sí, ní òkè Ọlọ́run tòótọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́