-
Ẹ́kísódù 19:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí wọ́n múra sílẹ̀ de ọjọ́ kẹta, torí pé ní ọjọ́ kẹta, Jèhófà yóò sọ̀ kalẹ̀ sórí Òkè Sínáì níṣojú gbogbo àwọn èèyàn náà.
-
-
Ẹ́kísódù 25:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Màá pàdé rẹ níbẹ̀, màá sì bá ọ sọ̀rọ̀ látorí ìbòrí náà.+ Láti àárín àwọn kérúbù méjì tó wà lórí àpótí Ẹ̀rí náà ni màá ti jẹ́ kí o mọ gbogbo ohun tí màá pa láṣẹ fún ọ pé kí o sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
-