ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 30:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Kí o gbé e síwájú aṣọ ìdábùú tó wà nítòsí àpótí Ẹ̀rí,+ níwájú ìbòrí tó wà lórí Ẹ̀rí, níbi tí màá ti pàdé rẹ.+

  • Léfítíkù 16:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Sọ fún Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ pé kó má kàn wá sínú ibi mímọ́+ tó wà lẹ́yìn aṣọ ìdábùú+ nígbàkigbà, níwájú ìbòrí Àpótí, kó má bàa kú,+ torí màá fara hàn nínú ìkùukùu*+ lórí ìbòrí+ náà.

  • Nọ́ńbà 7:89
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 89 Nígbàkigbà tí Mósè bá lọ sínú àgọ́ ìpàdé láti bá Ọlọ́run*+ sọ̀rọ̀, ó máa ń gbọ́ ohùn tó ń bá a sọ̀rọ̀ láti òkè ìbòrí+ àpótí Ẹ̀rí, láàárín àwọn kérúbù+ méjèèjì; Ọlọ́run á sì bá a sọ̀rọ̀.

  • Àwọn Onídàájọ́ 20:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Lẹ́yìn náà, àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà,+ torí àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́ wà níbẹ̀ nígbà yẹn.

  • Sáàmù 80:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 80 Fetí sílẹ̀, ìwọ Olùṣọ́ Àgùntàn Ísírẹ́lì,

      Ìwọ tí ò ń darí Jósẹ́fù bí agbo ẹran.+

      Ìwọ tí ò ń jókòó lórí* àwọn kérúbù,+

      Máa tàn yanran.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́