ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 13:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Kélẹ́bù wá gbìyànjú láti fi àwọn èèyàn náà lọ́kàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe dúró níwájú Mósè, ó sọ pé: “Ẹ jẹ́ ká gòkè lọ láìjáfara, ó dájú pé a máa gba ilẹ̀ náà, torí ó dájú pé a máa borí wọn.”+

  • Nọ́ńbà 14:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+

  • Nọ́ńbà 14:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àmọ́ ó dájú pé Jóṣúà ọmọ Núnì àti Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè, tí wọ́n wà lára àwọn ọkùnrin tó lọ ṣe amí ilẹ̀ náà máa wà láàyè.”’”+

  • Nọ́ńbà 34:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí ẹ mú ìjòyè kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tó máa pín ilẹ̀ tí ẹ máa jogún+ fún yín. 19 Orúkọ àwọn ọkùnrin náà nìyí: látinú ẹ̀yà Júdà,+ Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè;

  • 1 Kíróníkà 4:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn ọmọ Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè ni Írù, Élà àti Náámù; ọmọ* Élà sì ni Kénásì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́