Nọ́ńbà 13:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà tí wọ́n dé Àfonífojì Éṣíkólì,+ wọ́n gé ẹ̀ka àjàrà tó ní òṣùṣù èso àjàrà kan, méjì lára àwọn ọkùnrin náà sì fi ọ̀pá gbọọrọ kan gbé e, pẹ̀lú pómégíránétì díẹ̀ àti èso ọ̀pọ̀tọ́+ díẹ̀.
23 Nígbà tí wọ́n dé Àfonífojì Éṣíkólì,+ wọ́n gé ẹ̀ka àjàrà tó ní òṣùṣù èso àjàrà kan, méjì lára àwọn ọkùnrin náà sì fi ọ̀pá gbọọrọ kan gbé e, pẹ̀lú pómégíránétì díẹ̀ àti èso ọ̀pọ̀tọ́+ díẹ̀.