Nọ́ńbà 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Àfonífojì Éṣíkólì,+ tí wọ́n sì rí ilẹ̀ náà, wọ́n kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n má bàa lọ sí ilẹ̀ tí Jèhófà fẹ́ fún wọn.+
9 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Àfonífojì Éṣíkólì,+ tí wọ́n sì rí ilẹ̀ náà, wọ́n kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n má bàa lọ sí ilẹ̀ tí Jèhófà fẹ́ fún wọn.+