Àwọn Onídàájọ́ 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Júdà tún lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Hébúrónì jà (Kiriati-ábà ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀), wọ́n sì pa Ṣéṣáì, Áhímánì àti Tálímáì.+
10 Júdà tún lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Hébúrónì jà (Kiriati-ábà ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀), wọ́n sì pa Ṣéṣáì, Áhímánì àti Tálímáì.+