Ẹ́kísódù 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+ Sáàmù 78:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó fi ìkùukùu* ṣamọ̀nà wọn ní ọ̀sán,Ó sì fi ìmọ́lẹ̀ iná ṣamọ̀nà wọn ní gbogbo òru.+
21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+