ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 29:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Kí o fi ọmọ àgbò àkọ́kọ́ rúbọ pẹ̀lú nǹkan wọ̀nyí: ìyẹ̀fun kíkúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà* tí o pò mọ́ ìlàrin òṣùwọ̀n hínì* òróró tí wọ́n fún àti ọrẹ ohun mímu tó jẹ́ wáìnì tó kún ìlàrin òṣùwọ̀n hínì.

  • Léfítíkù 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “‘Tí ẹnì* kan bá fẹ́ mú ọrẹ ọkà+ wá fún Jèhófà, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná, kó da òróró sórí rẹ̀, kó sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀.+

  • Léfítíkù 2:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “‘Ẹ má ṣe mú ọrẹ ọkà kankan tó ní ìwúkàrà+ wá fún Jèhófà, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ mú kí àpòrọ́ kíkan tàbí oyin èyíkéyìí rú èéfín bí ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́