-
Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.”
-
-
Nọ́ńbà 7:54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Ní ọjọ́ kẹjọ, Gàmálíẹ́lì+ ọmọ Pédásúrì, ìjòyè àwọn ọmọ Mánásè
-
-
Nọ́ńbà 10:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Gàmálíẹ́lì+ ọmọ Pédásúrì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Mánásè.
-