-
Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 1:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 nínú àwọn ọmọ Jósẹ́fù: látinú ẹ̀yà Éfúrémù,+ Élíṣámà ọmọ Ámíhúdù; látinú ẹ̀yà Mánásè, Gàmálíẹ́lì ọmọ Pédásúrì;
-