ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Yóò wà ní iwájú orí Áárónì, kí Áárónì sì máa ru ẹ̀bi ẹni tó bá ṣe ohun tí kò tọ́ sí àwọn ohun mímọ́,+ èyí tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yà sí mímọ́ nígbà tí wọ́n fi ṣe ẹ̀bùn mímọ́. Kò gbọ́dọ̀ kúrò níwájú orí rẹ̀, kí wọ́n lè rí ojú rere Jèhófà.

  • Léfítíkù 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “‘Wọ́n gbọ́dọ̀ máa ṣe ojúṣe wọn sí mi, kí wọ́n má bàa tipa bẹ́ẹ̀ ṣẹ̀, kí wọ́n sì kú torí rẹ̀, torí pé wọ́n sọ ọ́ di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà, tó ń sọ wọ́n di mímọ́.

  • Nọ́ńbà 18:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Àwọn ọmọ Léfì fúnra wọn ni kó máa ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé, àwọn sì ni kó máa dáhùn fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Àṣẹ tó máa wà títí lọ jálẹ̀ gbogbo ìran yín ni pé wọn ò gbọ́dọ̀ ní ogún láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́