-
Diutarónómì 18:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Wọn ò ní fún àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì àti gbogbo ẹ̀yà Léfì pátá ní ìpín tàbí ogún kankan ní Ísírẹ́lì. Wọ́n á máa jẹ lára àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, èyí tó jẹ́ tirẹ̀.+ 2 Torí náà, wọn ò gbọ́dọ̀ ní ogún kankan láàárín àwọn arákùnrin wọn. Jèhófà ni ogún wọn, bó ṣe sọ fún wọn.
-