ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Áárónì lọ pé: “O ò ní ní ogún ní ilẹ̀ wọn, o ò sì ní ní ilẹ̀ kankan tó máa jẹ́ ìpín rẹ+ láàárín wọn. Èmi ni ìpín rẹ àti ogún rẹ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

  • Nọ́ńbà 18:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Torí mo ti fi ìdá mẹ́wàá tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa mú wá fún Jèhófà ṣe ogún fún àwọn ọmọ Léfì. Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún wọn pé, ‘Wọn ò gbọ́dọ̀ ní ogún+ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.’”

  • Diutarónómì 10:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìdí nìyẹn tí wọn ò fi fún Léfì ní ìpín tàbí ogún kankan pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀. Jèhófà ni ogún rẹ̀, bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sọ fún un.+

  • Jóṣúà 13:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì nìkan ni kò pín ogún fún.+ Àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn,+ bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+

  • Jóṣúà 13:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Àmọ́ Mósè ò fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì ní ogún kankan.+ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+

  • 1 Kọ́ríńtì 9:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́