- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 19:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 “‘Kí èyí jẹ́ àṣẹ tí wọ́n á máa tẹ̀ lé títí lọ: Kí ẹni tó ń wọ́n omi ìwẹ̀mọ́+ fọ aṣọ rẹ̀, kí ẹni tó sì fara kan omi ìwẹ̀mọ́ jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́. 
 
-