-
Diutarónómì 34:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ọgbọ̀n (30) ọjọ́+ sunkún torí Mósè ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù. Nígbà tó yá, ọjọ́ tí wọ́n fi ń sunkún, tí wọ́n sì fi ń ṣọ̀fọ̀ torí Mósè dópin.
-