-
Nọ́ńbà 20:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Nígbà tí gbogbo àpéjọ náà wá rí i pé Áárónì ti kú, gbogbo ilé Ísírẹ́lì sunkún nítorí Áárónì fún ọgbọ̀n (30) ọjọ́.+