Ẹ́kísódù 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí i, wọ́n ń bi ara wọn pé, “Kí nìyí?” torí wọn ò mọ ohun tó jẹ́. Mósè sọ fún wọn pé: “Oúnjẹ tí Jèhófà fún yín pé kí ẹ jẹ ni.+ Nọ́ńbà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ ní báyìí, a* ti ń kú lọ. A ò rí nǹkan míì jẹ yàtọ̀ sí mánà+ yìí.” Sáàmù 78:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó ń rọ̀jò mánà sílẹ̀ fún wọn láti jẹ;Ó fún wọn ní ọkà ọ̀run.+ 25 Àwọn èèyàn jẹ oúnjẹ àwọn alágbára;*+Ó pèsè èyí tó pọ̀ tó kí wọ́n lè jẹ àjẹyó.+
15 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí i, wọ́n ń bi ara wọn pé, “Kí nìyí?” torí wọn ò mọ ohun tó jẹ́. Mósè sọ fún wọn pé: “Oúnjẹ tí Jèhófà fún yín pé kí ẹ jẹ ni.+
24 Ó ń rọ̀jò mánà sílẹ̀ fún wọn láti jẹ;Ó fún wọn ní ọkà ọ̀run.+ 25 Àwọn èèyàn jẹ oúnjẹ àwọn alágbára;*+Ó pèsè èyí tó pọ̀ tó kí wọ́n lè jẹ àjẹyó.+