-
Jẹ́nẹ́sísì 22:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Áńgẹ́lì Jèhófà tún pe Ábúráhámù lẹ́ẹ̀kejì láti ọ̀run,
-
-
Nọ́ńbà 22:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àmọ́ Ọlọ́run sọ fún Báláámù pé: “O ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé wọn lọ. O ò gbọ́dọ̀ gégùn-ún fún àwọn èèyàn náà, torí ẹni ìbùkún+ ni wọ́n.”
-