Nọ́ńbà 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè àti Áárónì pé: “Torí pé ẹ ò fi hàn pé ẹ gbà mí gbọ́, ẹ ò sì fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ ò ní mú ìjọ yìí dé ilẹ̀ tí màá fún wọn.”+ Diutarónómì 3:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+
12 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè àti Áárónì pé: “Torí pé ẹ ò fi hàn pé ẹ gbà mí gbọ́, ẹ ò sì fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ ò ní mú ìjọ yìí dé ilẹ̀ tí màá fún wọn.”+
27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+