ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!

  • Àwọn Onídàájọ́ 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ tí onídàájọ́ náà bá kú, wọ́n á tún bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìbàjẹ́ tó ju ti àwọn bàbá wọn lọ ní ti pé, wọ́n á máa tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì, wọ́n á máa sìn wọ́n, wọ́n á sì máa forí balẹ̀ fún wọn.+ Wọn ò fi ìwà wọn àti agídí wọn sílẹ̀.

  • Sáàmù 14:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé:

      “Kò sí Jèhófà.”+

      Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;

      Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́