Jẹ́nẹ́sísì 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Bábélì,*+ torí ibẹ̀ ni Jèhófà ti da èdè gbogbo ayé rú, ibẹ̀ sì ni Jèhófà ti tú wọn ká sí gbogbo ayé.
9 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Bábélì,*+ torí ibẹ̀ ni Jèhófà ti da èdè gbogbo ayé rú, ibẹ̀ sì ni Jèhófà ti tú wọn ká sí gbogbo ayé.