1 Sámúẹ́lì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé, ‘A ti dẹ́ṣẹ̀,+ nítorí a ti fi Jèhófà sílẹ̀ lọ sin àwọn Báálì+ àti àwọn ère Áṣítórétì;+ ní báyìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí a lè sìn ọ́.’ 1 Sámúẹ́lì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹ má ṣe lọ máa tẹ̀ lé àwọn ohun asán*+ tí kò ṣàǹfààní,+ tí kò sì lè gbani, nítorí pé asán* ni wọ́n jẹ́.
10 Wọ́n ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé, ‘A ti dẹ́ṣẹ̀,+ nítorí a ti fi Jèhófà sílẹ̀ lọ sin àwọn Báálì+ àti àwọn ère Áṣítórétì;+ ní báyìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí a lè sìn ọ́.’
21 Ẹ má ṣe lọ máa tẹ̀ lé àwọn ohun asán*+ tí kò ṣàǹfààní,+ tí kò sì lè gbani, nítorí pé asán* ni wọ́n jẹ́.