1 Sámúẹ́lì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kò sí ẹni tí ó mọ́ bíi Jèhófà,Kò sí ẹlòmíràn, àfi ìwọ,+Kò sì sí àpáta tí ó dà bí Ọlọ́run wa.+