Nọ́ńbà 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jóṣúà+ ọmọ Núnì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Mósè láti kékeré fèsì pé: “Mósè olúwa mi, pa wọ́n lẹ́nu mọ́!”+ Nọ́ńbà 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+ Nọ́ńbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+
30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+