Jẹ́nẹ́sísì 49:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Dánì+ tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì+ máa ṣèdájọ́ àwọn èèyàn rẹ̀.