Diutarónómì 33:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ó sọ nípa Dánì pé:+ “Ọmọ kìnnìún ni Dánì.+ Ó máa bẹ́ jáde láti Báṣánì.”+