Òwe 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tọ́ ọmọdé* ní ọ̀nà tó yẹ kó tọ̀;+Kódà tó bá dàgbà, kò ní kúrò nínú rẹ̀.+ Éfésù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+
4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+