ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 17:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ká sọ pé ọkùnrin tàbí obìnrin kan wà láàárín rẹ, nínú èyíkéyìí lára àwọn ìlú rẹ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, tó ń ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ, tó sì ń tẹ májẹ̀mú rẹ̀ lójú,+ 3 tó wá yà bàrá, tó sì lọ ń jọ́sìn àwọn ọlọ́run míì, tó ń forí balẹ̀ fún wọn tàbí tó ń forí balẹ̀ fún oòrùn tàbí òṣùpá tàbí gbogbo ọmọ ogun ọ̀run,+ ohun tí mi ò pa láṣẹ.+

  • 2 Àwọn Ọba 17:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Wọ́n ń pa gbogbo àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run wọn tì, wọ́n sì ṣe ère onírin* ọmọ màlúù méjì,+ wọ́n ṣe òpó òrìṣà,*+ wọ́n ń forí balẹ̀ fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run,+ wọ́n sì ń sin Báálì.+

  • Ìsíkíẹ́lì 8:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, ó mú mi wá sí àgbàlá inú ní ilé Jèhófà.+ Ní ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì Jèhófà, láàárín ibi àbáwọlé* àti pẹpẹ, nǹkan bí ọkùnrin mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) wà níbẹ̀ tí wọ́n kẹ̀yìn sí tẹ́ńpìlì Jèhófà, tí wọ́n sì kọjú sí ìlà oòrùn; wọ́n ń forí balẹ̀ fún oòrùn níbẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́