2 Kíróníkà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ó sì sọ pé: “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ṣebí ìwọ ni Ọlọ́run ní ọ̀run;+ ṣebí ìwọ lò ń ṣàkóso lórí gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè?+ Ọwọ́ rẹ ni agbára àti okun wà, kò sì sẹ́ni tó lè dojú kọ ọ́.+
6 ó sì sọ pé: “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ṣebí ìwọ ni Ọlọ́run ní ọ̀run;+ ṣebí ìwọ lò ń ṣàkóso lórí gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè?+ Ọwọ́ rẹ ni agbára àti okun wà, kò sì sẹ́ni tó lè dojú kọ ọ́.+