Léfítíkù 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso.